Opolopo awon agba oje ninu egbe oloselu PDP lo peju sibi ayeye ifeyinti Gomina Ayodele Fayose to waye lana ni ile itura Sheraton Hotel, ni ilu Abuja.
Awon to peju si be ni Uche Secondus, Yakubu Dogara, Senator Dino Melaye, Femi Fani Kayode ati awon bebelo.
Comments
Post a Comment