Ojogbon Kayode Fayemi eni ti awon omo ipinle Ekiti dibo yan gege bi Gomina ipinle na ninu eto idibo to koja ni ipinle na ni won tin se ayeye ibura fun ni gbangban fun ni ilu Ado olu-ilu ipinle na.
Kayode Fayemi ni yo bere ise gege bi Gomina ipinle na lati oni lo titi di odun merin ton bo. Eku orire o.
Kayode Fayemi ni yo bere ise gege bi Gomina ipinle na lati oni lo titi di odun merin ton bo. Eku orire o.
Comments
Post a Comment