Ayeye igbeyawo tunutn ti waye laafin Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi leyin igba ti igbeyawo re forisanpon ni nkan odun kan seyin. Igbeyawo na waye laarin Kabiyesi na ati arabirin ajihinrere Naomi Oluwaseyi, ojise olorun ati oludasile ijo nla kan ni ilu Akure.
Opolopo atotonu lo ti waye lori igbeyawo na latari bi ojise olorun o se se igbeyawo pelu oni isese ati alase ikeji orisa. Adura wa ni wipe ki Olorun bawon gbe ile won ro. Amin.
Comments
Post a Comment