Eto isinku arabirin Efemena Okedi, iyawo ologbe Ras Kimono lo waye loni ni ite igbokusi t Atan cemetery, ni Yaba
Arabirin Efemena Okedi ni o je iyawo keta ologbe na ati wipe iwadi fi han wipe oun ni ayo ologbe na. Ojise Olorun to waasu nibi eto isinku na lo fi idi re mule wipe oniwa tutu ati olufe eniyan ni arabirin na je ki olojo to de.
O wa ro awon molebi ati ololufe idile na lati se arikogbon wipe ba fe, ba ko, ojo kan la kuro laye.

Comments
Post a Comment