Ninu afihan agbejade mohun-maworan kan ti odomode kunrin olorin WIZ KID sese gbejade to pe akole re ni FEVER ni akegbe re Tiwa Savage ti gbe laruge ti won si jo fi ife jan si ara won.
Ife laarin awon olorin mejeji yi po de bi wipe awon ololufe won ti bere sini fura siwon wipe won tin gbe nkan gba eyin adogan. Sugbon fidio na ta lenu yeri-yeri be obe alata suwe-suwe.
Comments
Post a Comment