Gbajugbaja olorin takasufe Kanye West ati iyawo re Kim Kardashian lo se abewo si Aare orilede Uganda Yoweri Museveni




Idunu ati ayo ni Aare orilede Uganda ogbeni Yoweri Museveni fi gba alejo awon tokotaya olokiki lati orilede America Kanye West ati Kim Kardashian ni ile ijoba to wa ni orilede na.

Ninu ipade na, Aare na ki won ku ise takun-takun, o si ro won lati gbiyanju lati gbe eto oro asa ati idaraya orilede Uganda ati gbogbo orilede adulawo lapapo ga. Ogbeni Kanye fi bata Yeezy Boost se ebun fun Aare na, Aare bakana si fun won ni maalu mewa ati iwe re ti akole re n'je "Sowing the Mustard Seed".

Comments