Minisita fun eto asa ati ikede Alhaji Lai Mohammed, ninu atejade kan to se lori iku arabirin Hauwa Leman eni ti awon agbesunmomi Boko Haram pa ni ale ojo aje.
Ninu atejade na, o fi han wipe iwa ika gba ati wipe ibanuje nla ni iku arabirin na je fun gbogbo omo orilede Nigeria. O gbiyanju ninu atejade na lati ba awon molebi, ore ati awon ololufe odomode birin na kedun iku omo na. O si gbadura wipe Olorun o fi ori ji omo na, yo si fun wa ni isegun lori oro awon agbesunmomi Bokoharam ton fi ojojumo pele si.
Atejade na ni yi ni ede geesi;

''It is very unfortunate that it has come to this. Before and after the deadline issued by her abductors, the Federal Government did everything any responsible government should do to save the aid worker. As we have been doing since these young women were abducted, we kept the line of negotiations open all through. In all the negotiations, we acted in the best interest of the women and the country as a whole. We are deeply pained by this killing, just like we were by the recent killing of the first aid worker. However, we will keep the negotiations open and continue to work to free the innocent women who remain in the custody of their abductors,'' the Minister said.
Comments
Post a Comment