Ilu Jerusalemu ni adari egbe ajijagbara fun orilede Biafra Nnamdi Kanu wa
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Awon aworan tuntun kan jeyo loni lori ero ayelujara instagram to si fi han wipe alafia ni ogbeni Nnamdi Kanu, adari egbe ajijagbara fun orilede Biafra eni ti awon omo ologun Nigeria tin wa lati odun to koja wa.
Comments
Post a Comment