Oni ni ayeye ojo ibi odun kẹ́rìndínlọ́gọ́rin oserebirin agba Iya Rainbow






Agba ogbontarigi oserebirin Idowu Philips eni ti inagi re je Iya Rainbow loni n'se ayeye ojobi odun kẹ́rìndínlọ́gọ́rin re. 

O se atejade kan lori ero ayelujara Instagram o se bere lowo awon ololufe re wipe se oun jo omo odun merindinlogorin.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

''HAPPY BIRTHDAY TO ME ???????????????????????????????? DO I LOOK 76YRS ???? MY FANS FRIENDS FOLLOWERS TELL ME''

Comments