Aare Buhari ti de orilede Faranse fun ipade alakoko Paris Peace Forum





Aare orilede Nigeria Muhammadu Buhari ti de orilede Faranse lati kopa nibi ipade alakoko Paris Peace Forum.

Ipade na o da lori bi idagbasoke yo se wa laarin igbayegbepo ati ibasepo laarin awon Aare orilede gbogbo agbaye.

Comments