Aare Buhari ti pade de orilede Nigeria leyin abewo olojo marun to se lo si orilede Faranse



Leyin ipade, apero ati abewo ti Aare orilede Nigeria, Buhari lo se pelu awon adari orilede gbogbo agbaye se, Aare na ti de pada si orilede Nigeria leyin ojo karun.

Awon to peju si papako ofurufu lati ki Aare na kaabo ni Gomina ipinle Katsina Aminu Bello Masari, Gomina ipinle Ekiti Kayode Fayemi atiGomina ipinle  Anambra Willie Obiano.

Comments