Aare Buhari ti yan Musa Abaji gege bi adajo agba

Ninu atejade kan ti Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ka si etigbo awon omo ile igbimo asofin, o fi han wipe Aare orilede Nigeria Muhamadu Buhari ti yan adajo Musa Abaji gege bi adajo agba ile ejo to wa ni ilu Abuja.

Atejade na fi han wipe yiyan Musa Abaji gege bi adajo agba na je eleyi to te le ofin orilede Nigeria.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

“In line with 1999 constitution upon the advice of the National Judicial Council, I hereby refer for confirmation the appointment of Justice Musa Abaji as the Justice of the Supreme Court of Nigeria. While hoping that this is expeditiously considered by the Senate, accept the assurances of my highest regard”.

Comments