Ogbontarigi ati afinju akotan Stan Lee ti ku. Omo odun marundilogorun ni akowe na ki olojo to de.
Stan Lee je ikan ninu awon to kopa ribiribi lati ri wipe cinima agbelewo te siwaju ni orilede America. Ninu awon sinima agbelewo to ti kopa ni Black Panther, Spider-Man, X-Men, Mighty Thor, Iron Man, Fantastic Four, Incredible Hulk, Daredevil Ant-Man ati bebe lo.
Ile iwosan Cedars-Sinai Medical Center ni orilede Los Angeles ni alagba Stan lee ku si. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire.

Comments
Post a Comment