An wa arakunrin Damilola Ogunjobi

Awon molebi arakunrin Damilola Ogunjobi omo odun metalelogun kan ti ke gbajari wipe awon n wa arakunrin na lati bi ose kan gbako ni ipinle Eko.

Gege bi atejade ti awon molebi arakunrin na se, won so wipe arakunrin na lo jade ni ile re to wa ni Berger ni ipinle Eko lo si ibise re ni agbegbe Alausa ti ko si ti pada wale lati ojo na. 

Won wan ro enikeni to ba ri arakunrin na, ko kan si ile ise olopa to ba sunmo won, tabi ko pe awon ago wonyi 08053221435, 08056151598 or +234 705 071 3686. E se.

A o ni sonu o. Amin
 

Comments