Arakunrin Oyemykke ati ogbeni Tunde Ednut ti kan arawon labuku (ARADUGBO E GBA MI)

Ogbontarigi soro-soro Oyemykke ti faraya yana-yana latari enu ete ti akegbe re ogbeni Tunde Ednut fi kan leyin igba ti faran kan jade nibi ti won ti le Oyemykke jade nibi ayeye ipade ti odomode olorin Wande Coal se ni ilu London.

Tunde Ednut ninu atejade kan to se lo fi idi re mule wipe looto ni won le Oyemykke jade latari wipe ko ri owo iwole san nibi ipade itagbangba ti Wande Coal fi lole.

Eyi lo ka Oyemykke lara, to si kan akegbe re Tunde Ednut ni abuku to po, orisirisi oruko lo ti pe, to si tu asiri re wipe igara olosa ni ogbeni Tunde.

Comments