Awon aworan nibi ayeye ifilole iwe Aare nigbakanri Goodluck Jonathan


 Aare orilede Nigeria nigbakanri. Goodluck Ebele Jonathan lo se ifilole iwe adako re to pe akole re ni My Transition Hours  ni o waye ni ile itura Transcorp Hilton Hotel ni ilu  Abuja.

Opolopo awon eyan jankan,jankan ati awon oloselu nla bi Atiku Abubakar, Abdusalami Abubakar, Yakubu Gowon, Adams Oshimole,  Bukola Saraki,  Yakubu Dogara, ti Boss Mustapha si soju Aare Buhari.












Comments