Edakun, se akara oyinbo ni eleyi abi kengbe akara?

Iyalenu nla lo je nigba ti akara oyinbo ti won gbe koju Aremo Charles eni to se abewo ranpe si orilede Nigeria de ori ero ayelujara.

Opolopo awon eyan to ri akara oyinbo na lo je kayefi fun, ti won sin bere wipe se akara oyinbo re abi kengbe akara?

Awon atejade kookan niyi lori ero ayelujara twitter;

See anything wrong with this cake made to welcome Prince Charles and The Duchess of Cornwall to Nigeria?

Comments