#El-Zakzaky3.5million Opuro aye ati orun ni Lai Mohammed- Reno Omokri lo so be


Ogbeni Reno Omokri ninu atejade to se lori ero ayelujara twitter loni lo ti bu enu ate lu atejade kan ti ogbeni Lai Mohammed se nigba ton ba awon akoroyin soro.

 Ninu faran na, ni a ti ri gbo wipe owo toto million meta abo naira 3.5million naira ni won fin bo adari iko Shitte Ibrahim EL-Zakzaky ni ososu.


Ogbeni Reno Omokri so wipe opuro eyan jati-jati gba ni Lai Mohammed ati wipe ijoba Buhari o fi igbaye gbadun awon osise ijoba ni orilede yi sokan.

Comments