Gbajugbaja odomodebirin olorin Chidinma ti ko ile awosifila fun Iya re


Oni, ojo kewa osu kokanla ni oje ojo ti Iya odomodebirin olorin Chidinma arabirin  Martha Ekile n'se ayeye ojo ibi ọgọta odun re. 

Odomodebirin na ninu atejade to se lori ero ayelujara instagram lo se afihan ile awosifila to sese ko fun iya re, to si fi adura ti nidi wipe isu omo a pe lenu Iya na. O dupe gidigidi fun gbogbo iyanju ati ilakaka ati akitiyan ti Iya re ti se lori re.

Eku ori ire o.

Comments