Gbajugbaja olorin Duncan Mighty ra oko ayokele tuntun fun iya arugbo kan

Ninu atejade kan ti gbajugbaja odomodekunrin olorin Duncan Mighty se lori ero ayelujara instagram, o se afihan iya arugbo kan nibi to tin fese rajo si orin tuntun to sese gbe jade Miekeraso.

O be awon ololufe re ki won ba wadi ibi ti iya arugbo na n'gbe lati fun ni ebun, leyin igba to ri iya na ni o fi oko ayokele tuntun Camry da iya na lola.

Opolopo awon lo ti fi adura ran Duncan mighty lowo tatari ebun to fun iya arugbo na.

Comments