Linda Ikeji ti bo aso loju Eegun instablog9ja

Leyin atotonu opolopo awon eniyan lati wadi eni to ni ile ise iroyin ori ero ayelujara Instablog9ja,  ogbontarigi bulooga Linda Ikeji ti to pinpin, o si ti fi idi re mule wipe ogbeni John Abayomi Aruleba lo ni ile ise na.

Opolopo awon eyan lo ti wa faraya lori oro na ti won si tin so opolopo oro nipa arakunrin na. Awon oro na ni yi;





Comments