Oni ni ayeye ojo ibi gbajugbaja olorin Davido

Oni, ojo kokanlelogun osu kokanla ni ojo ibi gbajugbaja odomodekunrin olorin Davido.

Omo odun merindinlogbon ni odomodekunrin na pe. Adura wa fun ni wipe ki olorun tunbo ma bukun re si lojojumo. Amin.

Comments