Uchenna Iyawo ogbontarigi alawada Ajebo ti keko gboye ni ile iwe giga BOWEN

Ogbontarigi alawada ti inagi re nje Ajebo lo se atejade lori ero ayelujara lati ki iyawo re Uchenna ku orire latari ikeko jade re kuro ni ile iwe giga BOWEN unifasiti.

O so siwaju si ninu atejade na wipe arabirin na lo gba ami eye to dara julo laarin awon akegbe re
Atejade na ni yi ni ede geesi;

GUESS WHO JUST BAGGED 1ST CLASS HONORS IN STATISTICS..???? @uchae_erem

I'm so proud of you wifey.. The maths way I no know, God you don collect am for 2 of Us.
BRAINS AND BEAUTY, WHAT MORE CAN A MAN ASK FOR??

Comments