Gomina ipinle Sokoto, Aminu Tambuwal, ninu atejade kan to se lori ero ayelujara twitter lo fi han wipe Aare orilede Nigeria nigbakanri Alhaji Shehu Shagari ti pa ipo da.
O so siwaju si wipe ile iwosan ijoba apapo to wa ni ilu Abuja ni ologbe na dake si. Omo odun metalelaadọrun ni ologbe na ki olojo to de.
Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin

Comments
Post a Comment