Aare orilede Nigeria nigbakanri Goodluck Jonathan ati iyawo re lo se abewo si ile alaja meje to wo ni ipinle Rivers
Isele buruku kan sele ni nkan bi ago meta osan ana ni agbegbe New GRA ni Port Harcourt ipinle Rivers nigba ti ile alaja meje kan wo lu awon osise ile na. Okere tan awon eyan ọgọ́rùn ni ile na wo lu ti akitiyan si ti bere lati dola emi won
Aare Orilede Nigeria nigbakanri Ebele Jonathan ati iyawo re Patience lo sibe laro oni lati lo se abewo, lati si lo ba won kedun ati lati gbiyanju pelu bi won o sele ran won lowo.
Aare Orilede Nigeria nigbakanri Ebele Jonathan ati iyawo re Patience lo sibe laro oni lati lo se abewo, lati si lo ba won kedun ati lati gbiyanju pelu bi won o sele ran won lowo.
Comments
Post a Comment