Afinju sorosoro Toolz ati oko re Tunde Demuren ti bi omokunrin lanti-lanti December 16, 2018 Get link Facebook X Pinterest Email Other Apps Tolu Demuren eni ti gbogbo eyan mo si Toolz ati oko re Tunde Demuren ti bi omokunrin lanti-lanti kan ni ilu Oyinbo. Awon ololufe mejeji yi ni won se igbeyawo ni odun 2016 ti olorun si fun won ni omokunrin alalubarika ni irole ana. Eku orire o. Comments
Comments
Post a Comment