KERESIMESI
Keresimesi keresimesi de
Keresimesi de
Abi olugbala kan fun wa
Ni ilu bethleham
Eni ti yio je oba aye ra ye raye
Awa ti ri irawo re ni awo sanmo
A si wa lati mu ebun fun oba ti abi loni.
Kristi alagbawi Eda
Kristi alagbada ina
Kristi aiku ,aisa
Kristi olugbala Eda Eledumare.
Aku odun Keresimesi o, Odun a yabo fun gbogbo wa
Comments
Post a Comment