Amaka ti doju ti gbajugbaja olorin Peruzzi

Iyalenu nla lo je nigba ti aworan gbajugbaja odomodekunrin olorin Peruzzi jade nibi ti o tin fi enu ko arabirin kan ti oruko re nje Tobi Jacobs lenu.

Ni tooto, arabirin na lo ya aworan na, to si gbe si ori ero ayelujara instagram, sugbon opolopo awon akegbe re bi Davido ati bebe lo ti fi abuku kan odomode olorin na.

Afi igba ti AMAKA DOJU TI PERUZZI.

Comments