Awon agbebon yin ibon pa oloselu kan ni ipinle Ekiti

Awon agbebon kan ti yin ibon pa oloselu ati cansilo ijoba ipinle Ado ni ipinle Ekiti, ogbeni Deji Adeyanju. Iyawo ologbe na ninu atejade to se fun awon agbofinro so wipe isele na sele ni nkan bi ago mewa abo ale nigba ti oun ati ologbe na sokale lori okada niwaju ile won.

Ni kete ti won so kale ni awon agbebon na sina ibon bole, ti won si yinbon pa arakunrin na.
Awon agbofinro ti wa bere iwadi to peye lori oro na, won si ti pinu lati mu awon odaran na, ki won si fi oju won ba ile ejo..

Comments