Awon agbofinro ti mu awon eyan merin ti won fura si wipe won lowo ninu iku ogagun Alex Badeh

Awon eyan merin ti wa ni atimole awon olopa ni ilu Abuja latari wipe won fura si won wipe won lowo ninu iku ogagun Alex Badeh eni ti awon agbenipa gba emi re ni ojo kejidinlogun osu yi.

Iwadi ati iforowanilenuwo ti wa bere lori oro na, won si ti pinu lati wadi oro na finifini, ki won si fi oju awon koloransi na jofin.

Comments