Aworan nibi abewo ti Aare Buhari se si awon molebi ologbe Shehu Shagari



Aare orilede Nigeria Muhamadu Buhari  lana lo se abewo si awon molebi ologbe Shehu Shagari eni to ti fi igba kan je Aare orilede Nigeria ri lati ba won kedun iku ologbe na.

Ninu oro re, o ki won ku araferakun, o si gbadura wipe Olorun o je ki ojo jina sira o. Amin.


Comments