Chike, omo agba oloselu Edwin Clark ti ku

Ibanuje dori agbakodo nigba ti iroyin iku Chike omokunrin omo odun metalelogoji agba oje ninu oselu oloye Edwin Clark to wa leti.

Gege bi atejade ti awon molebi ologbe na se, won fi han wipe arakunrin Chike lo ku si ile iwosan aladani kan to wa ni ipinle Edo, leyin aisan ranpe kan. Won si gbadura wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments