Emi gan-gan le'mi won o ni fi elo mi se mi - Aare Buhari lo so be

Aare Buhari nibi abewo to se lo si orilede Poland lo se atejade kan lati fi da gbogbo eyan loju wipe oun o kin se sigidi gege bi awon alatako oun ti se n so.

O so siwaju si wipe emi gan-gan le'mi, won o ni fi elomi se mi, wipe oun si tin mura lati se ayeye ojo ibi odun kerindinlogorin oun ninu osu yi.

O so wipe Buhari ni oruko oun, oun o mo ibi ti won ti ri Jubril lati orilede Sudan o.

Comments