Gbajugbaja olorin Timaya ra oko ayokele G-Wagon ati Maybach lati se ayeye odun keresi


Ogbontarigi ati gbajugbaja olorin Timaya ti se odun keresimesi fun ara re nigba to ra oko ayokele bogini meji G-wagon ati Maybach .

Odomodekunrin na lo se afihan awon aworan na lori ero ayelujara instagramu re lati dupe lowo Olorun fun ore ofe ati ibunkun ojojumo.

Awa na ba olorire yo o.

Comments