Ijakadi waye laarin Yemi alade ati akegbe re Tiwa Savage nitori ikebe



Ninu atejade kan ti gbajugbaja odomodebirin olorin Yemi Alade se lori eroayelujara twitter, o so lerefe wipe ki awon olorin paapa julo awon obirin dekun si ki won ma fi ikebe tan awon ololufe won je. O so siwaju si wipe ikebe iro ni opolopo awon olorin na nlo, eleyi ti ko si ba oju mu.

Ni kete ti akegbe re Tiwa Savage fi eti ko oro na, lo se atejade lori instagramu re lati kilo fun Yemi Alade wipe ko lo so ewe agbeje mo owo.

Comments