Ile ejo ti sun igbejo adajo agba Paul Usoro siwaju


Adajo agba Hassan Muslim ti sun igbejo Aare egbe awon adajo (Nigeria Bar Association) Paul Usoro siwaju si ojo kejidinlogun osi kejila odun 2018 ni ile ejo agba kan to wa ni Ikoyi ni ipinle Eko.

Adajo agba Paul Usoro ni won ti fi esun jibiti ati esun ikowo to to Billionu kan abo dollar (1.5billion naira) to je owo ipinle Akwa Ibom je. Iwadi to peye tin lo lori oro na lati odo awon osise EFCC won ti pinu lati fi idi otito mule, ki won si di ododo mu.

Comments