Luca Modric lo gba ami eye agbaboolu to dangajia julo ni agbaye nibi ayeye Ballon d'Or awards

Luca Modric, omo egbe agbaboolu orilede Croatia ati egbe agbaboolu Real Madrid lo pegede gege bi agbaboolu to dara julo ni agbaye to si gba ami eye Ballon d'Or awards.

Modric lo gba ami eye na leyin igba to fi iga gbaga pelu awon akegbe re bi  Ronaldo, Antoine Griezmann, Kylian Mbappe ati Lionel Messi.

O dupe lowo awon ololufe ati alatileyin re, o si fi da won loju wipe oun o ni ja won kule.

Comments