Ojogbon Sophie Oluwole (Mamalawo) ti ku

Ojogbonbirin Sophie Oluwole eni ti inagi re nje Mamalawo ti ku. 

Iroyin fi to wa leti wipe ojo ketalelogbon osu kejila yi ni iya na fi aye sile leyin aisan ranpe kekere kan. 

Omo odun metalelogorin ni ologbe na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments