Oma se o! Odomodekunrin agunbaniro kan so emi re nu ninu ijamba oko ni ipinle Kano



Ibanuje nla lo je nigba ti iroyin iku odomodekunrin agunbaniro kan ti oruko re nje Enoch Noah to wa leti.

Odomode kunrin na eni ton pada si enu ise re leyin igba to rin irinajo lo si ipinle Kogi lo so emi re ni nigba ton pada lo si ipinle Kano ni opopona Kogi si Abuja.

Opolopo awon molebi ati ore re lo ti wa fi ihunu han ti won si ki wipe o digba o se. Adura wa ni wipe ki Olorun foriji ologbe na, ko si petu si okan awon obi re. Amin.

Comments