Ninu atejade ati afihan aworan ti odomodekunrin olorin
Ayoleyi Hanniel Solomon ti inagi re nje Reekado Banks se lori ero ayelujara instagram, o fi han wipe oni ni ojobi odun karundinlogbon re.
O dupe lowo Olorun fun ife ati ore ofe ojojumo ti oun ri gba.
Comments
Post a Comment