Ijamba ina kan to waye ninu oja Keffi ni ipinleNasarawa ni opolopo awon dukia ti sofo. Ibanuje ati iyalenu nla lo je fun awon oloja ton ta oja ninu oja Keffi na.
Iwadi ti wa bere lati mo nkan to se okunfa ijamba ina na nitori igba karun ti isele buruku yi yo sele ninu odun yi.
Comments
Post a Comment