Opolopo awon eyan farapa ninu ijamba oko kan to waye lori afara Third Mainland bridge ni ipinle Eko



Opolopo awon eyan lo farapa yanayana ninu ijamba oko kan to waye laarin oko akero kan ati oko ayokele lori afara Third Mainland bridge loni ni ipinle Eko.

Awon ti oro na se oju won so wipe ere asapajude ti awako oko akero na sa, lo fa ijamba oko na. Awon eleso abo ilu ati awon osise  Rapid Response Squad ti wa gbe awon to farapa lo si ile iwosan fu  itoju to peye.

Comments