Oserebirin Funke Akindele ti bi ibeji lanti-lanti (Ayo abara tintin)

Idunu ati ayo ni gbajugbaja oserebirin Funke Akindele eni ti inagi re nje Jenifa ati oko re JJC skillz fi se afihan wipe awon ti bi omokunrin ibeji lanti-lanti.

Ile iwosan aladani kan ni ilu oyinbo ni won bi awon omo na si, Iya ati awon omo ibeji na si wa ni ayo ati alafia. Eku orire o.

Comments