Aare Buhari ati akegbe re Atiku, ko orin won kere si numba wa nibi eto iforojomitoro-oro awon oludije fun ipo Aare orilede Nigeria #2019Debate
Eto iforojomitioro-oro to waye laarin awon oludije fun ipo Aare orilede Nigeria ni ojo kokandinlogun osu yi ni awon oludije gboogi labe egbe oloselu APC Muhamadu Buhari ati akegbe re lati egbe oloselu PDP ti ko lati ye won si.
Awon oludije meta bi Arabirin Ezekweseli, Fela Durotoye ati Kingsley Moghalu fi omoluabi won han ti won si pan awon alatileyin won le nigba ti won gbiyanju lati wa fun eto na.
Oludije labe egbe oloselu PDP, Atiku Abubaka eni ti irohin fi to wa leti wipe o sese kuro ni orilede America ti o si de ibi ti eto na ti waye lo ko lati soro latari wipe akegbe re Muhamadu Buhari na ko wa.
Orisirisi atejade ni awon omo orilede Nigeria ti bere sini ko sori ero ayelujara lati fi ibanuje ati edun okan won han.
Comments
Post a Comment