Ajo EFCC ti gbe ogbeni Doyin Okupelo si ile ejo fun esun jibiti to-to ẹ̀ẹ́dẹ̀gbẹ̀rin milionu naira



Gege bi atejade ti ajo EFCC se jade, won fihan wipe awon ti gbe ikan lara awon osise gbogi Aare orilede nigbakanri Goodluck Ebele Jonathan ogbeni Doyin Okupe lo fi oju ba ile ejo latari esun jibiti to to ẹ̀ẹ́dẹ̀gbẹ̀rin milionu naira.

Atejade na fi han wipe awon ile ise meji  Value Trust Investment Ltd ati Abrahams Telecoms Ltd na wa lara awon ti won jo pawopo lu jibiti na.

Comments