Agba oloselu ati olori egbe oloselu APC Asiwaju Bola Hameed Tinubu, nigba ton ba awon omo egbe oloselu APC soro nibi iwode itagbangba egbe oloselu na to waye ni ipinle Borno ni o ti fi enu abuku kan Oloye Olusegun Obasanjo.
O so ninu atejade na wipe, alabuku ati oni yeye lasan-lasan ni Obasanjo ti ko si ye ki eni kankan fi eti si oro re rara. O so siwaju si wipe gbogbo igbiyanju Obasanjo lati da alafia orilede yi ru ni o ti ja si pabo, nitorina ni ara fin kan bi aja elekuku.
Atejade oro na ni yi ni ede geesi;
“I can hear the other expired leaders like Obasanjo, ranting and lying. Don’t believe him, don’t trust him, he is expired''

“When we came on board in 2015, we made promises to all Nigerians that as the sheep of this country, we are going to turn it to the right direction and we have done that. We are sweeping all the cobwebs of the collateral corruption, we are sweeping it away to give Nigerians a new life, new home and a solid foundation; that is what President Buhari is doing and we are 100 per cent with him. President Muhammadu Buhari has been upright, firm and has been steady, focused with a great vision for the betterment and progress of this country.
“We can recall the rigging in 2003 under Obasanjo, we also knew what happened in 2007 under President Obasanjo. 95 percent of you must come out and vote en mass for Buhari because no other president had upheld democratic principles like president Buhari.
“In 1985, we gave it to him but he cannot remembers even one day to recognised MKO’s mandate of June 12. Again, when he came back into power, we ask him for the recognition he failed. Who did it; President Buhari. declared June 12 as Democracy day to honour MKO Abiola,”.
Comments
Post a Comment