Ibanuje nla lo je nigba ti iroyin jade wipe ogbeni Ibrahim Isah, eni to je asoju orilede Nigeria si orilede Cote D'Ivoire ti ku.
Won so si waju si wipe arakunrin na lo sadede subu lule, lo si ku. Omo ogota odun ni ologbe na ki olojo to de. Adura wa ni wipe ki Olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.
Comments
Post a Comment