Oludije fun ipo Aare Atiku Abubakar ati Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki lo se abewo ranpe si orilede America



Oludije fun ipo Aare labe egbe oloselu PDP Atiku Abubakar pelu awon akegbe re bi Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki ati awon bebe lo, ni won lo se abewo olojo ranpe si orilede America.

Gege bi atejade ti won se lori ero ayelujara, won fi han wipe ipade to waye laarin awon ati awon oloselu agba ni ijoba orilede America.

Comments