Babajide Sanwo-Olu, ogbontarigi oni diri


Iyalenu nla lo je nigba ti aworan orisirisi oludije fun ipo Gomina ipinle Eko ogbeni Babajide Sanwo-Olu jade lori ero ayelujara.

Opolopo atotonu wayi loti n lo lori awon aworan na, awon miran lero pe eto idibo ton bo lona, lo fa idi ti Sanwo Olu fi di oni diri osan gangan.

Comments