Iko egbe agbaboolu Arsenal fi agba han iko egbe agbaboolu Chelsea nigba ti won na won ni omi ayo meji si odo (2-0)
Idije ifesewonse to waye laarin iko egbe agbaboolu Arsenal ati Chelsea lo pari si omi ayo meji si odo, nibiti Iko egbe agbaboolu Arsenal ti fi agba han awon akegbe won lati Chelsea.
Ogbeni Alexandre Lacazette lo koko gba omi ayo alakoko wole fun iko egbe agbaboolu Arsenal,ti Laurent Koscielny si je omi ayo elekeji.
Idunu ati erin lo wa ni eke awon agbaboolu Arsenal, ti awon akegbe won lati Chelsea fi kari wonu.

Comments
Post a Comment